John 17:20

Jesu gbàdúrà fún gbogbo onígbàgbọ́

20 “Kì sì í ṣe kìkì àwọn wọ̀nyí ni mo ń gbàdúrà fún, ṣùgbọ́n fún àwọn pẹ̀lú tí yóò gbà mí gbọ́ nípa ọ̀rọ̀ wọn;
Copyright information for YorBMYO